Previous Page  9 / 9
Information
Show Menu
Previous Page 9 / 9
Page Background

Page 9

The Islamic Bulletin

The Purpose Of Life

Ki Allah bukun fun wa. Ki Allah to wa sona.

Mo fe so fun gbogbo awon onkawe yi ti ki ise Musu-

lumi---Je olotito si ara re. Ro nipa ohun ti o ti ka. Mu

alaye yi pelu re ki o si ronu le lori. Joko pelu Musu-

lumi kan ki o si je ki won se alaye siwaju die si fun o

nipa ewa Islam. Gbe igbese ti o tele!

Ni igba ti o ba setan lati gba Islam ki o si di

Musulumi, we ara re ki o to di Musulumi. Gba Islam.

Mo nipa Islam. Ki o si je anfani ti Allah fi fun o, nitori

igbagbo ki I se ohun ti o le fi owo yepere mu. Ti o ko

ba fi se iwa wu, wa so orun didun re nu. Ki Allah to

wa sona. Ki Allah ran wa lowo. Mo si dupe fun anfani

yi lati ba yin soro ni pase iwe yi.

Ni igba ti o ba setan lati gba Islam ki o si di

Musulumi, we ara re ki o to di Musulumi. Gba Islam.

Mo nipa Islam. Ki o si je anfani ti Allah fi fun o, nitori

igbagbo ki I se ohun ti o le fi owo yepere mu. Ti o ko

ba fi se iwa wu, wa so orun didun re nu. Ki Allah to

wa sona. Ki Allah ran wa lowo. Mo si dupe fun anfani

yi lati ba yin soro ni pase iwe yi. ُ

السَلاَمُ عَلَيْكُمْ وَرَحْمَةُ اللهِ وَبَرَكَاتُه

Assalamu Alaikum wa rahmatullahi wa barakatuh

[Larubawa fun “Alaafia fun o ati pelu aanu Allah ati

ibukun Re.”]

Ti o ba fe di Musulumi tabi ti o ba nilo alaye nipa

Islam, jowo kowo ranse siwa lori info@islamicbulletin.

org

tabi ye wa wo lori

www.islamicbulletin.org www.islamicbulletin.org/purpose/yoruba/Flipping/purpose_yoruba/index.html http://www.islamicbulletin.org/purpose/shahada/sh_yoruba.mp4 http://www.islamicbulletin.org/yoruba/yoruba.htm http://www.islamicbulletin.org/newsletters/issue_24_yoruba/beliefs.aspx http://www.islamicbulletin.org/services/new_muslims/carla_yoruba.html http://www.islamicbulletin.org/services/foreign.htm